Yorùbá jé èdè tí ó dùún so, o sì n gbé àsà àti ìse wa láruge. Orísísi ònà ní èdè naa ti gbé wa láruge bíi tí Orin, ìkíini àt nípa èro amáyélujára. Sùgbón kámá puró, a gbódò kó yorùbá kí á tó lè só, ìdí tí mo se jé olùkó nìyen.
Orúko mi ni Ayomiposi Ajayi, Omo bíbí Nigeria ní mo jé, mo jé Yorùbá, ìpínlè Ekiti ni mo ti wa. Kíkó èdè Yorùbá jé Ohun tí mo féràn, mó dè ti n kó èdè yorùbá fún odún méwá pèlú òpòlopò àseyorí láárín àwon àkéekó mí láìsí ìdíwó tàbí ìjákulè.
Mo yege nínú ìdánwò ní ilé èkó gíga pèlú èesì tí ódára jù lo, mo sìti kó òpòlopò akeékó ní ilé èkó alákòbèré ati ilé èkó gíga kin tó tèsíwájú pèlú èkó mi ní váásitì
E jé ká sàwàrí èdè yorùbá papó;
Ònà tí n ó maa gbà kó àwon akékó mi ní láti maa kó won ní àwon nnkán tí won yòo fí maa sòrò, tí wón bá ti lè sòrò a ó má lo orísirísi òrò ní gbólóhùn, a ó sì má tùnmò òrò sí èdè gèésì àti sí èdè yorùbá.
Àwón èkó wa yóo ma mú orí wa yá, yóo sì tùn kó wa móra pèlú
Orísirísi ìwé ni a ó pèsè fún àwon akékó láti lè mú èkó wa yá
Awón akéekó mi ti n so yorùbá dáradára, wón si ti lé ní ogórún, èyí jé àmì ìdánilójú pé tìre yóo seése.
láìpé ìwo naa yóo ma so èdè yorùbá láìsí ìdíwó.
Yára láti fi orúko sílè pèlú wa fùn kilaasì