Mo je omo ipinle Yoruba latí orile Ede Nigeria,
Ede Yoruba je ede abinibi mi, Mo Se idanwo Ede Yoruba mo si se aseyege. Mo feran latí ma kọ awon eniyan ni Ede Yoruba ni Ona ti o rọrun gidigidi. Je ki a jo Se ise po ki o le ri pe Yoruba dun lede.
Alfabeti Ede Yoruba
Konsonati ati faweli Ede Yoruba
Ami o'un inu ede Yoruba
Fifi ami si awon Oro
Bi a Se le ko ati bi a Se le ka Ede Yoruba
Oruko ati dida nkan Mo
Ikini ni Ede Yoruba
Asa, ise ati Ewa ile Yoruba
Orin asayan
Ninu awon Ona orisi ti o wa, mo feran latí ma lo Orin, aworan nkan ko awon Omode nitori awon nkan wonyi ni o le mu won tete Yara mo ohun ti a ba nko won.
Mo tun feran lati ma fi Kiko Omode ni eko Se bi ere abi awada ki idani leko na ma BA su won.